Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 20:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àkókò náà yóò sì dé nítòótọ́ nígbà tí gbogbo ohun tí ó wà ní ààfin àti gbogbo ohun tí baba rẹ̀ ti kó pamọ́ sókè títí di ọjọ́ Òní, wọn yí ó gbe lọ sí Bábílónì, kò sí ohun tí yóò kù, ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin 2 Ọba 20

Wo 2 Ọba 20:17 ni o tọ