Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 20:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì náà béèrè pé, “Kí ni wọ́n rí ní ààfin rẹ?”“Wọ́n rí gbogbo nǹkan ní ààfin mi,” Heṣekáyà wí pé. “Kò sí nǹkankan lára àwọn ìṣúra tí èmi kò fi hàn wọ́n.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 20

Wo 2 Ọba 20:15 ni o tọ