Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 20:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ayé ìgbà wọ̀n-ọn-nì Heṣekáyà ṣe àìsàn ó sì wà ní ojú ikú. Wòlíì Àìsáyà ọmọ Ámósì lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ ó sì wí pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa sọ: tún ilé rẹ ṣe, ṣùgbọ́n ìwọ yóò kú; o kò níí gbádùn.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 20

Wo 2 Ọba 20:1 ni o tọ