Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 19:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó lè jẹ́ wí pé Olúwa Ọlọ́run yóò gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ olùdarí pápá, ẹni tí ọ̀gá rẹ̀, ọba Ásíríà, ti rán láti fi Ọlọ́run alààyè sẹ̀sín, yóò sì báa wí fún ọ̀rọ̀ ti Olúwa Ọlọ́run rẹ ti gbọ́. Nítorí náà gbàdúrà fún ìyókù àwọn tí ó wà láàyè.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 19

Wo 2 Ọba 19:4 ni o tọ