Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 19:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní alẹ́ ọjọ́ náà, ańgẹ́lì Olúwa jáde lọ ó sì pa ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án lé ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n ènìyàn ní ibùdó àwọn ará Aṣíríà. Nígbà tí wọ́n sì dìde dúró ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì níbẹ̀ ni gbogbo òkú wà!

Ka pipe ipin 2 Ọba 19

Wo 2 Ọba 19:35 ni o tọ