Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 19:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti inú Jérúsálẹ́mù ní àwọn ìyókù yóò ti wáàti láti orí òkè Ṣíónì ni ọ̀pọ̀ àwọn tí ó ṣá àsálà.Ìtara Olúwa àwọn ọmọ ogun yóò ṣe èyí.

Ka pipe ipin 2 Ọba 19

Wo 2 Ọba 19:31 ni o tọ