Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 19:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí yóò jẹ́ àmìn fún ọ, ìwọ Heṣekíàyà:“Ọdún yìí ìwọ yóò jẹ ohun tí ó bá hù fún rara rẹ̀,àti ní ọdún kejì ohun tí ó bá hù jáde láti inú iyẹn.Ṣùgbọ́n ní ọdún kẹta, gbìn kí o sì kórè,gbin ọgbà àjàrà kí o sì jẹ èṣo rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 19

Wo 2 Ọba 19:29 ni o tọ