Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 19:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ìwọ ti bú tí o sì kẹ́gàn rẹ̀?Lórí ta ni ìwọ ti gbé gbé ohùn rẹsókè tí ó sì gbé ojú sókè sí ọ ní ìgbéraga?Lórí ẹni mímọ́ ti Ísírẹ́lì!

Ka pipe ipin 2 Ọba 19

Wo 2 Ọba 19:22 ni o tọ