Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 19:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dẹtí sílẹ̀, Olúwa kí o sì gbọ́; la ojú ù rẹ, Olúwa, kí o sì rí i, gbọ́ ọ̀rọ̀ Ṣenakérúbù tí ó rán láti fi bú Ọlọ́run alààyè.

Ka pipe ipin 2 Ọba 19

Wo 2 Ọba 19:16 ni o tọ