Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 19:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé àwọn òrìṣà orílẹ̀ èdè tí a ti parun láti ọ̀dọ̀ àwọn babańlá mi gbà wọ́n là: òrìṣà Gósánì, Háránì Réṣéfù àti gbogbo ènìyàn Édẹ́nì tí wọ́n wà ní Télásárì?

Ka pipe ipin 2 Ọba 19

Wo 2 Ọba 19:12 ni o tọ