Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 16:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásì sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ ní ìlú Dáfídì: Heṣekáyà ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:20 ni o tọ