Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 16:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásì ọba sì gé igi-ìpílẹ̀ àwọn àgbédúró náà, ó sí agbada náà kúrò lára wọn; ó sì gbé agbada nlá náà kalẹ̀ kúrò lára àwọn màlúù idẹ tí ń bẹ lábẹ́ rẹ̀, ó sì gbé e ka ilẹ̀ tí a fi òkúta tẹ́.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:17 ni o tọ