Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún kejìdínlógójì Ásáríyà ọba Júdà. Ṣakaríà ọmọ Jéróbóámù di ọba Ísírẹ́lì ní Ṣamáríà, ó sì jọba fún oṣù mẹ́fà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:8 ni o tọ