Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 15:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ménáhémù fi agbára gba owó náà lọ́wọ́ Ísírẹ́lì. Gbogbo ọkùnrin ọlọ́lá ní láti dá àádọ́ta ṣékélì fàdákà láti fún ọba Áṣíríà. Bẹ́ẹ̀ ni ọba Áṣíríà padà sẹ́yìn, kò sì dúró ní ilẹ̀ náà mọ́.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:20 ni o tọ