Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 15:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣálúmù ọmọ Jábésì dìtẹ̀ sí Ṣakaríà. Ó dojúkọ ọ́ níwájú àwọn ènìyàn, ó sì pa á, ó sì jọba dípò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:10 ni o tọ