Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n nígbà tí ó di ọba, ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n. Orúkọ ìyá a rẹ̀ a máa jẹ́ Jéhóádínì; ó wá láti Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:2 ni o tọ