Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 13:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ohùn kan tí wọ́n fi sílẹ̀ ní ti ọmọ ogun Jéhóáhásì àyàfi àádọ́ta ọkùnrin ẹlẹ́ṣin, kẹ̀kẹ́ mẹ́wàá, àti ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ọmọ ogun ẹlẹ́sẹ̀, nítorí ọba Ṣíríà ti pa ìyókù run, ó sì ṣe wọ́n bí eruku nígbà pípa ọkà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:7 ni o tọ