Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa pèsè Olùgbàlà fún Ísírẹ́lì, wọ́n sì sá kúrò lọ́wọ́ agbára Ṣíríà. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbé nínú ilé ara wọn gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti wà tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:5 ni o tọ