Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olórí àwọn ọrọọrún ṣe gẹ́gẹ́ bí Jéhóíádà àlùfáà ti paà láṣẹ́. Olúkúlùkù mú àwọn ọkùnrin rẹ̀ àwọn tí ó ń lọ sí iṣẹ́ ìsìn ní ọjọ́ ìsinmi àti àwọn tí wọ́n wá sí ọ̀dọ̀ Jéhóíádà àlùfáà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 11

Wo 2 Ọba 11:9 ni o tọ