Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 11:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú pẹ̀lú u rẹ̀ àwọn olórí ọ̀rọọrún àti gbogbo balógun àti àwọn olùṣọ́ àti gbogbo àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà àti lápapọ̀, wọ́n mú ọba sọ̀kalẹ̀ wá láti ilé tí a kọ́ fún Olúwa. Wọ́n sì wọ inú ààfin lọ, wọ́n sì wọlé nípa ìlẹ̀kùn ti àwọn olùṣọ́. Ọba sì mú àyè rẹ̀ ní orí ìtẹ́ ọba.

Ka pipe ipin 2 Ọba 11

Wo 2 Ọba 11:19 ni o tọ