Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 11:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jéhóíádà dá májẹ̀mú láàrin Olúwa àti ọba àti àwọn ènìyàn tí yóò jẹ́ ènìyàn Olúwa. Ó dá májẹ̀mú láàrin ọba àti àwọn ènìyàn pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 2 Ọba 11

Wo 2 Ọba 11:17 ni o tọ