Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 11:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wò ó, níbẹ̀ ni ọba, tí ó dúró lẹ́bàá òpó, gẹ́gẹ́ bí àṣà ti rí. Àwọn ìjòyè àti àwọn afọ̀npè wà ní ẹ̀bá ọba, gbogbo àwọn ènìyàn ilé náà sì ń yọ̀ wọ́n sì ń fọ̀npè pẹ̀lú. Nígbà náà Ataláyà fa aṣọ ìgúnwà rẹ̀ ya. Ó sì kégbe pé, “Ọ̀tẹ̀! Ọ̀tẹ̀!”

Ka pipe ipin 2 Ọba 11

Wo 2 Ọba 11:14 ni o tọ