Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 10:35-36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

35. Jéhù sin mi pẹ̀lú baba a rẹ̀, a sì sin ín sí Ṣamáríà Jéhóáhásì ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

36. Àkókò tí Jéhù fi jọba lórí Ísírẹ́lì ní Ṣamáríà jẹ́ ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n.

Ka pipe ipin 2 Ọba 10