Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 10:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìlà-oòrùn ti Jọ́dánì ni gbogbo ilẹ̀ ti Gílíádì (ẹ̀kún ilẹ̀ ti Gádì, Rúbẹ́nì, àti Mánásè) láti Áróérì, tí ó wà létí Ánónì Gọ́ọ́jì láti ìhà Gílíádì sí Básánì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 10

Wo 2 Ọba 10:33 ni o tọ