Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 10:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì sọ fún Jéhù pé, “Nítorí ìwọ ti ṣe dáradára ní ṣíṣe èyí tí ó tọ́ ní ojú mi, tí o sì ti ṣe sí ilé Áhábù gẹ́gẹ́ bí gbogbo èyí tí ó wà ní ọkàn mi, àwọn ọmọ ọ̀ rẹ yóò jókòó lórí ìtẹ́ Ísírẹ́lì títí dé ìran kẹrin.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 10

Wo 2 Ọba 10:30 ni o tọ