Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí Áhásáyà ti ṣubú láàrin fèrèsé láti òkè yàrá rẹ̀ tí ó wà ní Ṣamáríà, ó sì fi ara pa. Ó sì rán oníṣẹ́, ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ lọ ṣe ìwádìí lọ́wọ́ Bálísébúbù, òrìṣà Ékírónì, bóyá èmi ó lè rí ìwòsàn ìfarapa yìí.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 1

Wo 2 Ọba 1:2 ni o tọ