Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì lo igi álígúmù náà láti fi ṣe àtẹ̀gùn fún ilé Olúwa àti fún ilé ọba àti láti fi ṣe dùùrù àti ohun ọ̀nà orin fún àwọn akọrin. Kò sì sí irú rẹ̀ tí a ti rírí ní ilẹ̀ Júdà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 9

Wo 2 Kíróníkà 9:11 ni o tọ