Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì gbé ọmọbìnrin Fáráò sókè láti ìlú Dáfídì lọ sí ibi tí ó ti kọ́ fún un, nítorí ó wí pé “Aya mi kò gbọdọ̀ gbé nínú ilé Dáfídì ọba Ísírẹ́lì nítorí ibi tí àpótí ẹ̀rí Olúwa bá tí wọ̀, ibi mímọ́ ni.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 8

Wo 2 Kíróníkà 8:11 ni o tọ