Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Sólómónì sì rúbọ ọrẹ ti ẹgbà á mọ́kànlá (22,000), orí màlúù àti àgùntàn àti ọkẹ́ mẹ́fà àgùntàn àti ẹranko. Bẹ́ẹ̀ ni ọba àti gbogbo àwọn ènìyàn ya ilé Ọlọ́run sí mímọ́.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 7

Wo 2 Kíróníkà 7:5 ni o tọ