Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n ṣé Ọlọ́run nítòótọ́ yóò máa bá àwọn ènìyàn gbé lórí ilẹ̀ ayé bí? Ọ̀run, àti ọ̀run gíga kò le gbà ọ́. Báwo ni ó ṣe kéré tó, ilé Olúwa tí mo ti kọ́!,

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:18 ni o tọ