Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nísinsinyìí Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, pa ìlérí tí ó ti ṣe mọ́ fún ìransẹ́ rẹ Dáfídì baba mi nígbà tí o wí pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ fẹ́ kù láti ní ọkùnrin láti jókòó níwájú mi lórí ìtẹ́ Isírẹ́lì, kìkì bí àwọn ọmọ rẹ tí wọ́n bá kíyèsíara nínú gbogbo ohun tí wọ́n ṣe láti rìn níwájú mi gẹ́gẹ́ bí òfin mi gẹ́gẹ́ bí o sì ti ṣe.’

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:16 ni o tọ