Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa sì ti mú ìléri rẹ̀ ṣẹ. Èmi ti dìde ní ipò Dáfídì baba mi, a sì gbé mi ka ìtẹ́ Ísírẹ́lì, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti ṣe ìlérí, èmi sì ti kọ́ tẹ́ḿpìlì fún orúkọ Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:10 ni o tọ