Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọ̀pá rẹ̀ náà gùn tó bẹ́ẹ̀ tí a fi rí ori àwọn ọ̀pá náà láti ibi àpótí ẹ̀rí náà níwájú ibi mímọ́ náà, ṣùgbọ́n a kò rí wọn lóde. Níbẹ̀ ni ó sì wà títí di òní yìí.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 5

Wo 2 Kíróníkà 5:9 ni o tọ