Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Sólómónì pe àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì jọ sí Jérúsálẹ́mù, gbogbo àwọn olórí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan àti àwọn olóyè àwọn ìdílé Ísírẹ́lì, kí wọn kí ó gbé àpótí ẹ̀rí Májẹ̀mu Olúwa gòkè wá láti síónì ìlú Dáfídì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 5

Wo 2 Kíróníkà 5:2 ni o tọ