Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Okùn náà dúró lóri akọ màlúù méjìlá, mẹ́ta kọjú sí àríwá, mẹ́ta kọjú sí ìwọ̀ oòrùn, mẹ́ta kọjú sí gúsù mẹ́ta kọjú sí ìlà oòrùn. Òkun náà sì sinmi lórí wọn àti gbogbo ìhà ẹ̀yìn wọn sì wà ní apá àárin.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 4

Wo 2 Kíróníkà 4:4 ni o tọ