Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 36:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jehóiakínì sì jẹ́ ẹni ọdún méjìdínlógún (18) nígbà tí ó di ọba, ó sì jẹ́ ọba ní Jérúsálẹ́mù fún oṣù mẹ́ta àti ijọ́ mẹ́wàá ó sì ṣe búburú ní ojú Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 36

Wo 2 Kíróníkà 36:9 ni o tọ