Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 34:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún kejìdínlógún ìjọba Jósíà ni a ti wẹ ilẹ̀ náà mọ́ àti ilé Olúwa, ó sì rán Ṣáfánì ọmọ Ásálíà àti Màséíà olórí ìlú náà, pẹ̀lú Jóà, ọmọ Jóáhásì, akọ̀wé, láti tún ilé Olúwa Ọlọ́run ṣe.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:8 ni o tọ