Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 34:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósíà sì kó gbogbo ohun ìríra kúrò nínú gbogbo ìlú tí ń ṣe ti àwọn tí ó wà ní Ísírẹ́lì, ó sì mú kí gbogbo àwọn tí ó wà ní Ísírẹ́lì sin Olúwa Ọlọ́run wọn gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe wà láyè wọn, kò yà kúrò láti máa tọ Olúwa Ọlọ́run àwọn baba wọn lẹ́yìn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:33 ni o tọ