Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 34:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì lọ sókè ní ilé Olúwa pẹ̀lú àwọn ọkùnrin Júdà, àwọn ènìyàn Jérúsálẹ́mù, àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì gbogbo ènìyàn lati ẹní ńlá sí ẹní kékeré, ó sì kà á ní etí wọn gbogbo ọ̀rọ̀ ínú ìwé májẹ̀mú, tí wọ́n ti rí nínú ilé Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:30 ni o tọ