Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 34:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ọkàn rẹ̀ dúró ìwọ sì rẹ ara rẹ sílẹ̀ níwájú Olúwa nígbà tí ó gbọ́ ohun tí ó sọ lórí ibíyìí àti ènìyàn rẹ, nítorí ìwọ rẹ ara rẹ sílẹ̀ níwájú mi tí o sì fa aṣọ rẹ ya, tí o sì lọ níwájú mi. Èmi ti gbọ́ tìrẹ ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:27 ni o tọ