Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 34:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ lọ kí ẹ lọ bérè lọ́wọ́ Olúwa fún mi fún àwọn ìyókù Ísírẹ́lì àti Júdà nípa ohun tí wọ́n kọ sínú ìwé yìí tí a ti rí. Títóbi ni ìbínú Olúwa tí ó ti jáde sí orí wa nítorí àwọn baba wa kò ti pa ọ̀rọ̀ Olúwa mọ́, wọn kò sì tíì ṣe gẹ́gẹ́ bí i gbogbo èyí tí a kọ sínú ìwé yìí.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:21 ni o tọ