Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 33:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi àwọn ọmọ rẹ̀ rúbọ nínú iná ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Bẹni-Hínómù, ó ń ṣe oṣó, àfọ̀ṣẹ, ìsàjẹ́ pẹ̀lú bíbéèrè lọ́dọ̀ àwọn abókúsọ̀rọ̀, àti ẹlẹ́mìí. O se ọ̀pọ̀ ohun búburú ní ojú Olúwa láti mú un bínú.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 33

Wo 2 Kíróníkà 33:6 ni o tọ