Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 33:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àdúrà rẹ̀ àti bí inú Ọlọ́run ṣe dùn sí àdúrà rẹ̀ àti gbogbo àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ àti àìsòótọ́ àti àwọn ipò níbi tí ó kọ́ àwọn ibi gíga sí, ó sì gbé àwọn òpó Áṣérà àti àwọn òrìṣà kí ó tó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, gbogbo rẹ̀ ni a kọ sínu ìwé ìrántí àwọn aríran.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 33

Wo 2 Kíróníkà 33:19 ni o tọ