Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 33:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ó mú àwọn pẹpẹ padà bọ̀ sípò. Ó sì rú ọrẹ ìdàpọ̀ àti ọrẹ ọpẹ́ lórí rẹ̀. Ó sì sọ fún Júdà láti sin Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 33

Wo 2 Kíróníkà 33:16 ni o tọ