Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 30:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí bí ẹ̀yin bá tún yípadà sí Olúwa, àwọn arákùnrin yín, àti àwọn ọmọ yín, yóò rí àánú níwájú àwọn tí ó kó wọn ní ìgbèkùn lọ, kí wọn kí ó lè tún padà wá sí ilẹ̀ yí: nítorí Olúwa Ọlọ́run yín, oníyọ́nú àti aláàánú ni, kì yóò sì yí ojú rẹ̀ padà kúrò lọ́dọ̀ yín, bí ẹ̀yin bá padà sọ́dọ̀ rẹ̀.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 30

Wo 2 Kíróníkà 30:9 ni o tọ