Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 30:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹ̀yin kí ó má sì ṣe dàbí àwọn baba yín, àti bí àwọn arákùnrin yín tí ó dẹ́sẹ̀ sí Olúwa, Ọlọ́run àwọn baba wọn, nítorí náà ní ó ṣe fi wọ́n fún ìdahoro bí ẹ̀yin ti rí.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 30

Wo 2 Kíróníkà 30:7 ni o tọ