Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 30:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí wọn kò lè pa á mọ́ ní àkókò náà, nítorí àwọn àlùfáà kò tí i ya ara wọn sí mímọ́ tó; bẹ́ẹ̀ ni àwọn ènìyàn kò tí ì kó ara wọn jọ sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 30

Wo 2 Kíróníkà 30:3 ni o tọ