Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 30:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hésékíà sì ránsẹ́ sí gbogbo Ísírẹ́lì àti Júdà, ó sì kọ ìwé sí Éfúráímù àti Mánásè, kí wọn kí ó wá sínú ilé Olúwa ní Jérúsálẹ́mù láti pa àjọ ìrékọjá mọ́ sí Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 30

Wo 2 Kíróníkà 30:1 ni o tọ