Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìloro tí ó wà níwájú ilé Olúwa náà jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn rékọjá fífẹ̀ ilé náà àti gíga rẹ̀ jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn rékọjá fífẹ̀ ilé náà àti gíga rẹ̀ jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́.Ó tẹ́ inú rẹ̀ pẹ̀lú kìkì wúrà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 3

Wo 2 Kíróníkà 3:4 ni o tọ