Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 28:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásì sì sùn pẹ̀lú àwọn Baba rẹ̀ a sì sin ín ní ìlú Jérúsálẹ́mù ṣùgbọ́n wọn kò mú un wá sínú àwọn ìsà òkú àwọn ọba Ísírẹ́lì. Heṣekáyà ọmọ rẹ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 28

Wo 2 Kíróníkà 28:27 ni o tọ